$ 0 0 Odù ifá tí ó sòkalè ni *ìretè-ìká* ifá pé ire aya (couples blessing) ifá ní a ó se òpòlopò Odún láyé. Ifá ní kí á rúbo lópòlopò wípé Odún yìí yóò sàn wá fún ajé, aya, Omo, ogbó ató àti àìkú tí se baálè orò . Àsèyí se àmòdún ooo